Recent Articles
Awọn onijagidijagan Al Shabab doju ija kọ ile ounjẹ kan ni Somalia
Awọn onijagidijagan Al Shabab ti pa eniyan eétàdílógún (17) nigba ti wọn doju ija kọ ile ounje kan ni Mogadishu olu ilu Somalia ni alẹ ojọ alamisi gẹgẹ bi awọn […]
Ile ẹjọ ti fun Olisa Metuh ni beeli ẹgbẹ̀ta millionu naira
Ile ẹjọ kan ni olu ilu Abuja ni ọjọ ẹti, ti fun akọwe agba ẹgbẹ PDP, Olisa Metuh, ni beeli ti apaọ rẹ jẹ ẹgbẹ̀ta millionu (600 million) naira pẹlu […]
Alaga ẹgbẹ APC sọ pe amuwa Ọlọrun ni iṣoro ti o doju kọ ọrọ aje wa.
John Odigie-Oyegun, Alaga ẹgbẹ APC sọpe inira ti o doju kọ orilede Naijiriya jẹ amuwa la ti ọdọ Ọlọrun lati ran wa leti pe a ni lati ṣe iyipada si […]