Ile ẹjọ ti fun Olisa Metuh ni beeli ẹgbẹ̀ta millionu naira
Ile ẹjọ kan ni olu ilu Abuja ni ọjọ ẹti, ti fun akọwe agba ẹgbẹ PDP, Olisa Metuh, ni beeli ti apaọ rẹ jẹ ẹgbẹ̀ta millionu (600 million) naira pẹlu […]
Ile ẹjọ kan ni olu ilu Abuja ni ọjọ ẹti, ti fun akọwe agba ẹgbẹ PDP, Olisa Metuh, ni beeli ti apaọ rẹ jẹ ẹgbẹ̀ta millionu (600 million) naira pẹlu […]
John Odigie-Oyegun, Alaga ẹgbẹ APC sọpe inira ti o doju kọ orilede Naijiriya jẹ amuwa la ti ọdọ Ọlọrun lati ran wa leti pe a ni lati ṣe iyipada si […]
Ile-ẹjọ to lọla ju ni ọjọ ọjọbọ ṣàrídájú idibo gomina ni ipinlẹ Imo, to gbe Ọgbẹni Rochas Okorocha wọle ni ọjọ kọkanla, oṣu kẹrin odun 2015. Ile ẹjọ naa ninu […]
Ẹgbẹ oṣelu PDP ti sọpe ẹtan lasan ni ogun ti iṣakoso Aare Muhammadu Buhari gbe kọ ibajẹ ẹ awọn oloṣelu. Eyii waye latari bi awọn EFCC sẹ mu ara igbimo […]